(a) Fa awon oro ti a seda yo ninu gbolohun yii.
(i) Isekuse kun owo awon omo yen
(ii) Agba wahala ni ainile.
(iii) Won maa n sanwo fun wa ni osoosu
(iv) Eda ko see gbe ara le.
(v) Ohun gbogbo lo gba ogbon.
Identification of derived words in given sentences and the morphemes in each word. Most candidates identified most of the words. Some candidates mistaking syllables for morphemes.