(a) Ṣe àpèjúwe àwọn ìró fáwẹ̀lì àránmúpè. (b) Fi àwọn fáwẹ̀lì náà hàn nínú ọ̀rọ̀ Yorùbá.
a) Description of nasalized vowels. Most candidates that attempted it were unable to describe the vowels precisely. (b) Making use of the nasalized vowels in words. Some of the candidates did fairly well.