waecE-LEARNING
Yoruba Paper 2,May/June. 2012  
Questions: 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 Main
General Comments
Weakness/Remedies
Strength
Conclusion








Question 4
SECTION A: EDE

Fa àpólà àpọ́nlé yọ nínú ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn gbólóhùn wọ̀nyí kí o sì sọ oríṣìí àpọ́nlé tó jẹ́:

  1.  Adéagbo sọ̀rọ̀ pẹ̀lú ìrẹ̀lẹ̀.
  2. Jùmọ̀kẹ́ ń rìn bí aláìsàn.
  3. Màá lọ sí oko.
  4. Bùkọ́lá hùwà rere nítorí ọjọ́ àtisùn.
  5. Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wà ní kíláàsì.
_____________________________________________________________________________________________________
Observation

(Identification of adverbial phrases and the types in given sentences.  Some candidates could not remember the various types.

Powered by Sidmach Technologies(Nigeria) Limited .
Copyright © 2015 The West African Examinations Council. All rights reserved.