waecE-LEARNING
Yoruba Paper 2,May/June. 2012  
Questions: 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 Main
General Comments
Weakness/Remedies
Strength
Conclusion








Question 5
SECTION A: EDE

()   Fa atọ́ka àsìkò àti ibá-ìṣẹ̀lẹ̀ inú ọ̀kọ̀ọ̀kan gbólóhùn wọ̀nyí yọ:

  1.  Wọ́n máa gbọ́ nípa ọ̀rọ̀ náà.
  2. Ọ̀gá ń bínú sí akẹ́kọ̀ọ́ náà.
  3. Bí wọ́n bá sọ bẹ́ẹ̀, wọ́n ti ba nǹkan jẹ́.
  4. Wọ́n á wá.
  5. Ṣọlá máa ń pọn omi tà.

 

(b)     Sọ irúfẹ́ àsìkò/ibá-ìṣẹ̀lẹ̀ tí atọ́ka kọ̀ọ̀kan fi hàn.

_____________________________________________________________________________________________________
Observation

 Identification of tense and aspect and the types in given sentences.  It was satisfactorily identified by many candidates but the types were not fully grasped by the candidates

Powered by Sidmach Technologies(Nigeria) Limited .
Copyright © 2015 The West African Examinations Council. All rights reserved.