Question 5
Se apejuwe okookan awon oro-oruko ti o wa ninu gbolohun wonyi. (i) Mo ri won. (ii)Se o ti jeun? (iii) A ri i ni oke oja. (iv) E ko mo wa ri. (v) Sola ri Bola ti o pon omo. (vi) Won n be yin.
OBSERVATION
Identification and description of pronouns in the given sentences. The pronouns were identified but not properly described.