(a) Báwo ni a ṣe ń kí ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn wọ̀nyi? (i) Àgbẹ̀ (ii) Alágbẹ̀dẹ (iii) Ọdẹ (iv) Onídìrí (v) Babaláwo (vi) Apẹja (vii) Aláró (viii) Amọ̀kòkò (ix) Akọ̀pẹ (x) Àwọn tí ó ń tayò
(b) Ni 13 (a) (i – x), bàwo ni ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ṣe ń dáhùn?
OBSERVATION
This is on specific traditional greetings for selected artisans in the society and the responses. Most candidates did well in the first part but performed poorly in the second part of the question.