waecE-LEARNING
Yoruba Paper 2, Nov/Dec. 2013  
Questions: 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 Main
General Comments
Weakness/Remedies
Strength
Conclusion




Question 4

Dárúkọ ìsọ̀rí tí ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ọ̀rọ̀ tí a fa ìlà sí nínú gbólóhùn wọ̀nyí wà ki o sì ṣàlàyé iṣẹ́ tí wọ́n ṣe.
(a)    Ṣọlá fẹ́ràn aṣọ funfun.
(ḇ      Bímpé má ṣe jẹ oúnjẹ yẹn o!
(d)    Ta ni ó  gbé àpótí sí ibẹ̀ yẹn?
(e)    Ìwọ ni ọkùnrin ọlọ́rọ̀ náà ń wá.
(ẹ)    Omi tútù wù míí mu.
(f)      Ẹ bá mi ra ẹja ńlá bọ̀.

 

 



OBSERVATION
Identify the word classes of the underlined words in the given sentences and explain the functions performed in each sentences. Most candidates passed in the first part but failed woefully in the second part. Grammatical functions were not properly understood.

 

_____________________________________________________________________________________________________
Powered by Sidmach Technologies(Nigeria) Limited .
Copyright © 2015 The West African Examinations Council. All rights reserved.