Fa awon awe-gbolohun afarahe ti o wa ninu awon gbolohun  isale wonyi yo, ki o si so orisi awe-gbolohun afarahe ti okookan je.
                        (a)Wale ti a n soro re ti de.
                        (b)Won ti sun ki a too de.
                        (d)A o ni jeun bi a ba de.
                        (e)Omo naa sare nigba ti o ri eegun.
                        (e)O ya won lenu pe mo di adajo.