Question 3
Fa àwọn awẹ́-gbólóhùn afarahẹ tí ó wà nínú ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn gbólóhùn wọ̀nyí yọ; kí o sì sọ oríṣi awẹ́-gbóló́hùn afarahẹ tí ó jẹ́.
(a) Màá gbowó tí o jẹ mí.
(b) Bí o bá fẹ́ o lè pè mí.
(d) Ó yà mí lẹ́nu pé Bùkọ́lá wá.
(e) Màá fẹ́yàwó kí n tó ra mọ́tò.
(ẹ) Fẹ́mi tí a ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ ti dé.
(f) Kàkà kí n jalè ma kúkú dẹrú.
Observation
Candidates are expected to identify the relative clauses in the given sentences and the types of relative clauses they are. Most of the candidates that attempted this question properly identified the relative clauses but failed to mention the types.