Question 5
Ṣe àpèjúwe àwọn ọ̀rọ̀-arọ́pò-orúkọ àti ọ̀rọ̀-arọ́pò afarajorúkọ tí ó wà nínú ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn gbólóhùn wọ̀nyí:
(a) Èmi ti gbà á.
(b) Àwa ti gbọ́.
(d) Wọn kì í gbọ́ràn bọ̀rọ̀.
(e) Òun gan-an ni mo fún un.
(ẹ) Ẹ̀yin wo ni ẹ̀ ń pariwo yẹn?
(f) Àwa ni oríire kàn.
Observation
Here, candidates were expected to identify and describe the pronouns and pronominal in the given sentences. The Pronouns and pronominal were properly identified but were poorly described by those candidates that attempted the question.