Yoruba Paper 2 WASSCE (PC), 2019

Question 7

Nínú oríkì “Ìran Ìrèmògún”, dárúkọ àwọn ohun tí ọ̀kọrin sọ pé ó gorí oyè lágbẹ̀dẹ.

 

 

Observation

 

Candidates were required to mention the important materials at the smithy mentioned by the poet.

            Àwọn ohun ti ọ̀kọrin sọ pé ó gorí oyè lágbẹ̀dẹ nínú Oríkì “Ìran Ìrèmògún”:

  1. Kóóko ẹ̀ẹ̀kan
  2. Ìrólé
  3. Ìràlé
  4. Bẹẹrẹ
  5. Omi agbada
  6. Àpáàdì
  7. Igi ọparun
  8. Awọ ẹtu
  9. Ògiri àlàpà
  10. Olúkóǹdó
  11. Ọmọ oówú
  12. Ìwàná
  13. Ẹ̀mú
  14. Ọ̀bẹṣìlò
  15. Gbàjámọ̀
  16. Àkànmọ́lẹ̀
  17. Igbá Arọ́

The important materials at the smithy as contained in the poem were not properly listed by most candidates due to poor knowledge of the text thereby resulting to a poor performance in question 7.