Question 2
Tún ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn wúnrẹ̀n  wọ̀nyí kọ ní àkọtọ́ òde-òní: 
(a)      àìyà
(b)     fún u
(d)     ga͂n
(e)      obìrin
(ẹ)      s̱ó̱
(f)      ḿ́bọ̀
(g)     ẹ̀nyin
(gb)    ọ̀ttà
(h)     ãnu
(i)      òshogbo
Observation
Candidates were  required to write the given words in mordern authography. 
     
Àtúnkọwúnrẹ̀nníàkọtọ́ òde-òní
| S/N | Àkọtọ́ àtijọ́ | Àkọtọ́ Òde-Òní | 
| a | àìyà | Àyà | 
| b | fún u | fún un | 
| d | gãn | gan-an | 
| e | obìrin | Obìnrin | 
| ẹ | ḿbọ̀ | ń bọ̀ | 
| f | s̱ó̱ | ṣọ́ | 
| g | ẹ̀nyin | ẹ̀yin | 
| gb | ọ̀ttà | Ọ̀tà | 
| h | ãnu | Àánú | 
| i | Òshogbo | Òṣogbo | 
Many of the candidates who attempted this question failed to tone mark their answers. This led to poor performance.
