Yoruba Paper 2 WASSCE (PC 2ND), 2022

Question 2

(a)   Kí ni afipè àsúnsí?
(b) Dárúkọ afipè àsúnsí fún ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ìró kọ́ńsónáǹtì wọ̀nyí:
(i)         t
(ii)        m
(iii)       k
(iv)       j
(v)        y
(vi)       l
(vii)      ṣ
(viii)     f
(ix)       gb


Observation

 

Candidates were required to define the term active articulators in (a) and identify the active articulators of the given consonant sounds in (b).

(a)        Afipè àsúnsí ni àwọn ẹ̀yà ara ìfọ̀ tí wọ́n máa ń gbéra nígbà tí a bá ń gbé ìró jáde/pe ìró. (Ìsàlẹ̀ ẹnu ni àwọn ẹ̀yà ara yìí máa ń wà).

(b)    


S/N

Kọ́ńsónáǹtì

Afipè Àsúnsí

i

t

iwájú ahọ́n

ii

m

ètè ìsàlẹ̀

iii

k

ẹ̀yìn ahọ́n

iv

j

ìwájú/àárín ahọ́n

v

y

àárín ahọ́n

vi

l

ìwájú ahọ́n

vii

àárín ahọ́n

viii

f

ètè ìsàlẹ̀

ix

Gb

ètè ìsàlẹ̀, ẹ̀yìn ahọ́n

Most of the candidates who attempted this question defined the active articulators but failed to identify the active articulators of the given consonants, this led to poor performance.