Yoruba Paper 2 WASSCE (PC), 2022

Question 4


Tọ́ka sí àwọn àpólà ìṣe inú ọ̀kọ̀ọ̀kan gbólóhùn wọ̀nyí
(a)         Wọ́n rò wá ro ire.
(b)        Àwọn ọba ṣe ìpàdé bòńkẹ́lẹ́.
(d)        Àwọn ọmọdé náà ti sùn.
(e)        Mo ra aṣọ tí ó tuntun.

(ẹ)         Túndé rí Dàda ní ọjà alẹ́
(f)         Màmá Ṣadé ń dín àkàrà
(g)        Ó fẹ́ràn owó.
(gb)       Ọmọ kan ké tòò!
(h)        Bímpé fi ara ṣiṣẹ́
(i)         Àwọn afẹ̀hónúhàn ba nǹkan jẹ́

Observation

 

Candidates were required to identify the verb phrase in each of the sentences.

          Àfàyọ àwọn àpólà ìṣe inú gbólóhùn:
(a)      rò wá ro ire
(b)     ṣe ìpàdé bòńkẹ́lẹ́
(d)     ti sùn
(e)      ra aṣọ tí ó tuntun
(ẹ)      rí Dàda/rí Dàda ní ọjà alẹ́
(f)      ń dín àkàrà
(g)     fẹ́ràn owó
(gb)    ké/ké tòò
(h)     fi ara ṣiṣẹ́/ṣiṣẹ́
(i)      ba nǹkan jẹ́

Many of the candidates who attempted this question could not differentiate between verb and verb phrase this led to loss of marks