Yoruba Paper 2 WASSCE (SC), 2016

Question 4

(a) Kí ni mọ́fíìmù?

(b) Pín ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ọ̀rọ̀ wọ̀nyí sí mọ́fíìmù:

(i) ìdárò;

(ii) ọ̀mùtí;

(iii) ilégbèé;

(iv) olópò;

(v) ẹranko;

(vi) òǹtàjà;

(vii) àìlówólọ́wọ́;

(viii) ọmọdékùnrin;

(ix) akọ̀pẹ;

(x) akọ̀wé;

(xi) pẹjapẹja;

(xii) ọmọkọ́mọ.

 

Observation

Candidates were expected to define morpheme and identify morphemes in the given words.  The first part was fairly answered, while the second part was poorly done.  Candidates mistook morpheme for syllable.