Yoruba Paper 2 WASSCE (SC), 2016

Question 5

Tọ́ka sí ọ̀rọ̀-àpọ́nlé àti ọ̀rọ̀-àpèjúwe tí ó wà nínú ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn gbólóhun wọ̀nyí; kí o sì sọ iṣẹ́ tí ọ̀kọ̀ọ̀kan ṣe níbẹ̀:

(a) Omí díẹ̀ ni ó tutù nini.

(b) Ajá dúdú sùn fọnfọn.

(d) Ẹja díndín wù mí í jẹ.

(e) Ara bàbá rere fà díẹ̀.

(ẹ) Àwọn sọ́jà kékeré kilẹ̀ kùù.

(f) Ọbẹ̀ ìyá mi ta sánsán.

 

Observation

Candidates were mandated to identify adjectives and adverbs in the given sentences as well as explain their functions in the various sentences where they occurred.  The first part was well tackled, but the second part was poorly handled.