Question 2
- Ṣàlàyé ní ṣokí sokí oríṣi àwọn ìró wọ̀nyí kí o sì fi àpẹẹrẹ méjì méjì kin àlàyé rẹ lẹ́yìn.
- .Fi àpẹẹrẹ méjì méjì hàn fún ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn wọ̀nyí:
(a)Ìró akùnyùn;
(b)Ìró àìkùnyùn.
(a)àsénupè;
(b)àfúnupè;
(c)àséèsétán.
Observation
Candidates were required to differentiate voiced and voiceless sounds with two examples each in (a) and to give two sounds each in relation to the given manner of articulation in (b). It was not fully grasped by those candidates that tackled the question; only few examples were correctly given.