Question 7
Nínú “Oríkì Ìran Olú-Òjé”, ṣàlàyé ìtàn tí ó rọ̀ mọ́ àyọlò ìsàlẹ̀ yìí.
“Ọmọ Elérubu èyí já ọ̀nà Ẹ̀yọ́
ọmọ òkúta-mẹ́ta ọ̀nà Lálámesè...”
Observation
This is an allusion behind the Ọmọ Elérubu... Candidates were required to narrate the allusion as evident in the oral poetry. Very few candidates showed evidence of proper study of the text.