Question 5
Ṣàlàyé ibá-ìṣẹ̀lẹ̀ wònyí kí o sì fi gbólóhùn méjì méjì ṣe àpẹẹrẹ ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn:
(a)Ibá-ị̀ṣẹ̀lẹ̀ àdáwà;
(b)Ibá-ị̀ṣẹ̀lẹ̀ bárakú;
(d) Ibá-ìṣẹ̀lẹ̀ atẹ́rẹrẹ;.
(e) Ibá-ìṣẹ̀lẹ̀ aṣetán.
Observation
Candidates were tasked to explain aspects in Yorùbá grammar and use the aspectual markers in sentences. Many candidates performed woefully as they misunderstood aspects for occurrence and could not come up with sentences containing each aspectual marker.