Question 4
Tọ́ka sí àpólà orúkọ nínú ọ̀kọ̀ọ̀kan gbólóhùn wọ̀nyí, kí o sì sọ iṣẹ́ tí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ṣẹ.
(a)Ìṣó ńlá gún Olú ní ẹsẹ̀.
(b)Mo ra aṣọ mẹ́ta.
(d) Ìsọ̀ ìyá Ìfẹ́ wà ní ọjà.
(e) Ọmọ ọ̀gá wá ra ìwé.
(ẹ) Iṣẹ́ náà ti tán.
Observation
The candidates were expected to identify the noun phrase and its function in each of the given sentences. Many of the candidates misunderstood noun phrases for nouns and the subject and object functions were not properly grasped.