Yoruba Paper 2 WASSCE (SC), 2016

Question 1

ÀRÒKỌ

Kọ àròkọ tí kò dín ní 300 ẹyọ ọ̀rọ̀ lórí orí-ọ̀rọ̀ kan ṣoṣo tí  o bá yàn.

(a) Ìrírí mi ní ọgbà ẹranko.

(b) Iṣẹ́ tí ó wù mí láti ṣe lójọ́ iwájú.

(d) Oúnjẹ ìbílẹ̀ dára ju oúnjẹ ilẹ̀ òkèèrè lọ.

(e) Ipa tí ìyàwó ń kó nínú ilé.

(ẹ) Kọ lẹ́tà sí ọ̀rẹ́ rẹ ní ilé-ẹ̀kọ́ mìíràn láti ṣe àlàyé fún un ohun tí o rò pé ó fa àìbọ̀wọ̀ fún olùkọ́ mọ́ ní àwọn ilé-ẹ̀kọ́ wa.

Observation

(a) This is a narrative essay on: My visit to a zoo.  Most candidates tackled the topic well, narrating individual experiences about their respective visits to a zoo.

(b) This is an expository essay on: Preferred career in future.  The topic was properly analysed by most of the candidates that attempted the question.

(d) An argumentative essay on: Local foods are more nutritious than foreign foods.  Most of the candidates that attempted this question limited themselves to one part instead of mentioning the pros and cons of both local and foreign foods, thereby limiting their scores to 50%.

(e)  The roles of a wife at home.  These roles were properly enumerated by most of the candidates that attempted it.

(ẹ)  An informal letter to your friend concerning the lack of respect for teachers by the students of nowadays.  It was adequately explained.