Yoruba Paper 2 WASSCE (SC), 2017

Question 4

(a) Kọ àpẹẹrẹ méjìméjì fún ọ̀kọ̀ọ̀kan ìsọ̀rí ọ̀rọ̀-orúkọ wọ̀nyí :

(i) ọ̀rọ̀-orúkọ aṣèbéèrè;

(ii) ọ̀rọ̀-orúkọ asọye;

(iii) ọ̀rọ̀-orúkọ afihàn;

(iv) òrọ̀-orúkọ ibìkan;

(b) Lo àpẹẹrẹ kọ̀ọ̀kan tí o kọ ni 4(a) ní gbòlóhùn afarahẹ tí òkọ̀ọ̀kan jẹ́;

 

Observation

(a) Candidates were required to give examples of the selected sub-classes of nouns and thereafter, use the given examples in sentences.
(b) Candidates attempted this question poorly in (a), which also reflected in their attempt to use the sub-classes of nouns to form sentences in (b), therefore leading to poor performance.