Yoruba Paper 2 WASSCE (SC), 2017

Question 5

(a) Tọ́ka sí irú gbólóhùn tí ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn wọ̀nyí jẹ́.

(i) Olú ni ó pa adìyẹ náà..

(ii) Ǹjẹ́ o ti jẹun?

(iii) Ẹ jókòó.

(iv) Ó níṣé àmọ́ kò lówó.

(v) Ajá gbó.


(b) Lo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn wọ̀nyí ní gbólóhùn

(i) tí...bá;

(ii) ìbáà;

(iii) ká ní;

(iv) yálà ... tàbí;

(v) kàkà kí.

 

Observation

Candidates were tasked to identify the type of given sentences in (a) and use the given grammatical items in (b) to form sentences.
Candidates’ performance was fairly good.