Yoruba Paper 2 WASSCE (SC), 2018

Question 13

Ṣàlàyé lórí ìwọ̀nyí gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà ìran-ara-ẹni lọ́wọ́:

  • Àáró;
  • Ìgbẹ́ ọdún dídẹ.

 

Observation

Candidates were expected to establish the explanation of Yorùbás’ belief in the life after death.


The expected answers are:


Ìgbàgbọ́ Yorùbá nínú Àṣẹ̀yìnwáyé:
i. Yorùbá gbàgbọ́ pé ara ènìyàn ló máa ń kú, kì í ṣe ẹ̀mí rẹ̀.
ii. Ẹ̀mí ẹni tí ó kú ṣì lè padà wá sáyé.
iii. Ẹ̀mí ọmọdé tí ó kú lè padà wá sí inú ìyá rẹ̀ kí ó tún bí i ní ọ̀tun léra léra (àbíkú)/(emèrè)/(ẹlẹ́gbẹ́ ọmọ).
iv. Bàbá àgbà/ìyá àgbà tó ti kú tó tún yà gẹ́gẹ́ bí ọmọ tuntun ní ọ̀ọ̀dẹ̀ ọmọ rẹ̀ bí àpẹẹrẹ: Babátúndé, Babájídé, Babátọ̀míwá, Ìyábọ̀dé, abbl jẹ́ àpẹẹrẹ àṣẹ̀yìnwáyé.
v. Ìgbàgbọ́ pé àwọn bàbá tí ó ti kú lè wá bẹ ará ayé wò ni ó bí Egúngún àti awo Orò tí à ń bọ.
vi. Ẹni tí ó ti kú lè lọ máa gbé níbò míràn (àkúdàáyà).
vii. Òkú lè wá láti bẹ àwọn ènìyàn rẹ̀ wò lójú àlá.
viii. A máa ń ṣe ètùtù òkú yíyà kí ẹ̀mí ẹni tó ti kú má baà máa yọ alààyè lẹ́nu
b.a. ìṣípà ọdẹ.
ix. Ẹ̀mí àwọn tí ó ti kú lè bá àwọn alààyè dá sí ọ̀rọ̀ tí wọ́n bá fi lọ̀ wọ́n.

 

Most of the candidates who chose this question did not quite understand it.
There is no evidence of their exposure to this aspect of Yorùbá culture.