Yoruba Paper 2 WASSCE (SC), 2018

Question 7

Nínú “Oríkì Ìran Olúfẹ̀”, kí ni àwọn ǹnkan tí akéwì ní ó buyì kún òòṣà?

 

Observation

Candidates were required to highlight the items which the songster enumerated as dignifying the divinity in Olúfẹ̀ Lineage verbal salute.


They were expected to give some of the following responses:


Àwọn ohun tí akéwì sọ pé ó buyì kún òoṣà ni:
(i) ṣẹ́ṣẹ́ ẹfun;
(ii) ààjà;
(iii) fífá orí apá kan dá apá kan sí;
(iv) ìkúnlẹ̀ rúmúrúmú;
(v) aṣọ funfun;
(vi) ‘héèpà òòṣà’;
(vii) iyán rúgúdú lọ́jọ́ ọ̀sẹ̀;
(viii) obì ifin;
(ix) obì ipa;
(x) adìẹ.

 

 

Most candidates who learnt from the text performed well, while those who failed to read the set text performed woefully.