Question 5  
                    (a)    Ṣàlàyé  ṣókí ṣókí lórí ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn  wúnrẹ̀n wọ̀nyí:
                        (i)   ẹ̀yán  ajórúkọ;
                        (ii)  ẹ̀yán aṣòǹkà;
                        (iii) ẹ̀yán  aṣàfihàn.
                        (b)    Fi  gbólóhùn méjìméjì ṣe àpẹẹrẹ ìlò ọ̀kọ̀ọ̀kan 5(a)(i-iii) kí o sì fàlà sí ọ̀rọ̀ tí o lò gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yán nínú  gbólóhùn náà.