Question 2
- Kí ni fóònù?
- Kí ni fóníìmù
-  Ṣe àdàkọ  àwọn lẹ́tà wọ̀nyí ní ìlànà fóníìmù:
 (i) ṣ (vi) un
 (ii) ọ (vii) y
 (iii) ẹ (viii) p
 (iv) j (ix) in
 (v) gb (x) l
Observation
Candidates were required to define phone in (a), phoneme in (b) and transcribe the letters in (d)
(a)      Fóònù: Èyí ni ìró kọ̀ọ̀kan tí a  máa ń gbé jáde nígbà tí a bá ń ṣe afọ̀. 
    
    (b)     Fóníìmù: Èyí ni àwọn ìró tí wọ́n  bá lè fi ìyàtọ̀ ìtumọ̀ hàn láàrin ọ̀rọ̀ kan àti òmíràn. 
(d) Àdàkọ àwọn ìró:
| S/N | ÌRÓ | ÀDÀKỌ ÌRÓ | 
| I | ṣ | /ʃ/ | 
| ii | ọ | /ɔ/ | 
| iii | ẹ | /ɛ/ | 
| iv | J | /ʤ/ /ɉ/ | 
| v | Gb | /g҇b/ | 
| vi | Un | /ũ/ | 
| vii | Y | /j/ | 
| viii | P | /k҇҇p/ | 
| ix | In | /ĩ/ | 
| x | L | /l/ | 
          
    Most  candidates who attempted this question failed because they mistook fóònù, a unit of sound in phonology,  for phone in telecommunication. They also missed out in transcription, thus  leading to their poor performance in this question. 
