Question 2
     Ṣe àpèjúwe àwọn fáwẹ̀lì wọ̀nyí: u, i, a, o, ẹ. an, ẹn, ọn, in, un.
Candidates were required to describe the vowels listed above.
Àpèjúwe àwọn ìró fáwẹ̀lì 
(i) / u / fáwẹ̀lì òkè/àhánupè ẹ̀yìn roboto àìránmúpè
(ii)  / i /  fáwẹ̀lì òkè/àhánupè iwájú pẹrẹsẹ àìránmúpè
(iii)    / a / fáwẹ̀lì odò/àyanupè àárín pẹrẹsẹ àìránmúpè 
(iv)    / o / fáwẹ̀lì ẹ̀bákè/àhánudíẹ̀pè ẹ̀yìn roboto àìránmúpè
 
(v)     /ẹ / fáwẹ̀lì ẹ̀bádò/àyanudíẹ̀pè ẹ̀yìn roboto àìránmúpè
 
(vi)    / an / fáwẹ́lì odò/àyanupè àárín pẹrẹsẹ àránmúpè
(vii)   / ẹn / fáwẹ́lì ẹ̀bádò/àyanudíẹ̀pè iwájú pẹrẹsẹ àránmúpè
(viii) / ọn / fáwẹ́lì ẹ̀bádò/àyanudíẹ̀pè ẹ̀yìn roboto àránmúpè
(ix)  / in /  fáwẹ́lì òkè/àyanupè iwájú pẹrẹsẹ àránmúpè
(x)  / un / fáwẹ́lì òkè/àhánupè ẹ̀yìn roboto àránmúpè
    
    
Observation
Many of the candidates who attempted this question could not give detailed description of the vowels.