Question 7
Nínú oríkì Ìran Olúkòyí”, dárúkọ mẹ́ta nínú àwọn òrìṣa tí bàbá wọn máa ń bọ kí ó tó lọ sí ojú ogun kí o sì sọ èèwọ̀ tí ó rọ̀ mọ́ òrìṣà kọ̀ọ̀kan tí o dárúkọ.
Candidates were required to mention three of the deities worshipped by the ancestors of Olúkòyí lineage before embarking on war and the taboo attached to each of the deities.
Òrìṣà tí bàbá àwọn Olúkòyí máa ń bọ kó tó lọ sí ojú ogun:
(i) Olúgbọ́n
(ii) Òòṣà Òkè
(iii) Àgbé
(iv) Òkè Ìbàdàn
Èèwọ̀ tí ó rọ̀ mọ́ òrìṣà kọ̀ọ̀kan:
(i) Olúgbọ́n: Tí wọ́n bá ń bọ Olúgbọ́n, wọn kò gbọdọ̀ gódó.
(ii) Òòṣà Òkè: Tí wọ́n bá ń bọ Òòṣà Òkè, wọn kò gbọdọ̀ lọlọ.
(iii) Àgbé: Tí wọ́n bá ń bọ Àgbé, wọn kò gbọdọ̀ pọnmi.
(iv) Òkè Ìbàdàn: Tí wọ́n bá ń bọ Òkè Ìbàdàn wọn kò gbọdọ̀ dáná
Observation
The candidates who attempted this question mentioned the deities but failed to mention the taboo attached to each of the deities thereby leading to poor performance.