Yoruba Paper 2 WASSCE (PC), 2016

Question 1

ÀRÒKỌ

Kọ àròkọ tí kò dín ní 300 ẹyọ ọ̀rọ̀ lórí orí-ọ̀rọ̀ kan ṣoṣo tí  o bá yàn.

(a) Àtubọ̀tán àìríṣẹ́ṣe àwọn akẹ́kọ̀ọ́jáde.

(b) Ètò ìsìnkú ìjòyè pàtàkì kan ní ìlú mi.

(d) Ilé-ìwòsàn ìjọba dára ju ti aládàáni lọ.

(e) Ìwúlò igi ọ̀pẹ.

(ẹ) Kọ lẹ́tà sí ọ̀rẹ́ rẹ tí ó wà ní ilẹ̀ òkèèrè láti ròyìn ayẹyẹ ìsọmọlórúkọ kan tí ó ṣojú rẹ.

Observation

(a) Aftermath of graduates’ joblessness in our society. The aftermaths were not properly enumerated by most of the candidates that attempted it.

(b) This is a narrative essay on: The burial ceremony of a prominent chief in candidates’ town. Most candidates that attempted it failed to write full length essays.

(d) An argumentative essay on: Government hospital is better than private hospital. Most of the candidates that attempted this question limited themselves to one part instead of mentioning pros and cons of both hospitals, thereby limiting their scores to 50%

(e)  Importance of palm tree. The essay was scanty as most of the candidates that attempted the question failed to write full essays.

(ẹ) An informal letter to a friend abroad, narrating events at a naming ceremony you attended recently. It was adequately addressed