Yoruba Paper 2 WASSCE (PC), 2016

Question 5

Fa ọ̀rọ̀-arọ́pò-orúkọ inú ọ̀kọ̀ọ̀kan gbólóhùn wọ̀nyí yọ; kí o sì ṣàlàyé irúfẹ́ ọ̀rọ̀-arọ́pò-orúkọ ti ọ̀kọ̀ọ̀kan jẹ́ àti iṣẹ́ tí ó ṣe nínú gbólóhùn tí ó ti jẹyọ.

(a) Ó ṣẹ̀ṣẹ̀ lọ ni.

(b) Ṣé ẹ ti ṣe tán.

(d) A pàdé yín lọ́nà lánàá.

(e) Títí fa ìwé mi ya.

(ẹ) Jídé bú wọn.

 

Observation

Candidates were tasked to identify the pronouns in the given sentences, mention the type and the function performed. The identification was fairly done, while the grammatical functions of the identified pronouns was not adequately grasped.