Yoruba Paper 2 WASSCE (PC), 2016

Question 4

(a) Kí ni awẹ́-gbólóhùn afarahẹ?

(b) (b) Fa àwọn awẹ́-gbólóhùn afarahẹ tí ó wà nínú àwọn gbólóhùn wọ̀nyí yọ; kí o sì sọ oríṣi awẹ́-gbólóhùn afarahẹ tí òkọ̀ọ̀kan jẹ́;

(i) Wọ́n ti sùn kí a tóó dé.

(ii) Ìbáà lówó kò lè jọba.

(iii) Wálé tí a ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ nìyí.

(iv) Tí ẹ bá lọ, ẹ bá mi ra nǹkan bọ̀.

(v) Ó dùn mọ́ àwọn òbí mi pé mo di adájọ́.

 

Observation

(a) Candidates were required to define subordinate clause. Some candidates did well in this part of the question.

(b) Identification of subordinate clauses and its functions in respective sentences. Identification of the subordinate clauses was relatively easy for the candidates but the function of each clause in its complex sentence was not properly understood by most of them.