Yoruba Paper 2 WASSCE (PC), 2016

Question 3

(a) Kí ni ìwúlò ìró ohùn gẹ́gẹ́ bí fóníìmù nínú èdé Yorùbá?

(b) Nipasẹ̀ bátànì ohùn, hun ọ̀rọ̀ mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ láti ara ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn sípẹ́lì wọ̀nyí; bi àpẹẹrẹ: oro = oró, òró, òro, orò: (i) ẹgbẹ; (ii) awo; (iii) ikun.

(d) Lo ọ̀kọ̀ọ̀kan ọ̀rọ̀ tí o hun ní ̣(b) ní gbólóhùn láti fi ìtumọ̀ wọn hàn.

 

Observation

(a) Most of the candidates that attempted the question mistook tones for phonemes for syllabification.

(b) Lack of in-depth knowledge of tone-marks was displayed by most of the candidates. Also,some of them misspelt the data given.

Poor performance in (a) and (b) resulted in woeful performance here.