Yoruba Paper 2 WASSCE (SC), 2018

Question 10

Nínú ewì “Ọ̀dàlẹ̀”, àwọn wo ni akéwì pè ní ọ̀dàlẹ̀?

 

Observation

This is a question that required the candidates to describe those who are seen as betrayers according to the poet.


The following are some of the points they were expected to mention:


Àwọn tí akéwì pè ní Ọ̀dàlẹ̀ nínú ewì “ Ọ̀dàlẹ̀” ni:
i. ẹni tí òun àti ọ̀rẹ́ rẹ̀ dòwò pọ̀ tí ó wá lẹ̀dí àpò mọ́ alágbèédá, tí ó sì sọ ọ̀rẹ́ rẹ̀ di ẹdun arinlẹ̀ jẹ́ ọ̀dàlẹ̀.
ii. Ọ̀dàlẹ̀ ọkọ níí bá aya ṣàdéhùn tí kì í pa á mọ́.
iii. Ọ̀dàlẹ̀ ọkọ níí máa á lu ìyàwó rẹ̀.
iv. Ọ̀dàlẹ̀ ìyàwó níí fi oorun jẹ ọkọ rẹ̀ níyà.
v. Ọ̀dàlẹ̀ ọkọ tàbí aya níí máaá yan àlè.
vi. Ọ̀dàlẹ̀ aya ni ó máa ń mú lára owó ọbẹ̀ pamọ́.
vii.Ọkọ tíí dá aṣọ rà sọ́rùn ara rẹ̀ nìkan jẹ́ ọ̀dàlẹ̀.
viii. Ọ̀dàlẹ̀ baálé níí fi owó ńlá jẹ pẹpẹsúùpù níta tí kò sì náání àtijẹ aya àtọmọ nílé.
ix. Ọ̀dàlẹ̀ ni òbí tó fọmọ rẹ̀ ṣọmọ ọ̀dọ̀.
x. Ọ̀dàlẹ̀ ni ìyàwó tó ya ọkọ rẹ̀ ní dìndìnrìn.

Candidates could not give the required answer due to shallow knowledge of the text.