Question 2
(a) Dárúkọ márùn-ún nínú àwọn ẹ̀ya-ara ifọ̀.
(b) Dárúkọ afipè àsúnsí àti àkànmọ́lẹ̀ fún ọ̀kọ̀ọ̀kan ìró wọ̀nyí
(i) / r /
(ii) / kp/
(iii) / g /
(iv) / d /
(v) / j /
Observation
Candidates were required to mention five of the numerous organs of speech in (a) and the active and passive articulators for the listed sounds in (b). (a) Àwọn ẹ̀yà-ara ifọ̀
(i) Erìgì
(xii) Kòmóòkun
(ii) Ètè òkè
(xiii) Ẹ̀ka kòmóòkun
(iii) Ètè ìsàlẹ̀ (xiv) Àlàfo tán-án-ná
(iv) Àfàsé
(xv) Gògòńgò
(v) Iwájú ahọ́n
(xvi) Káà ọ̀fun
(vi) Àárín ahọ́n
(xvii) Káà imú
(vii) Ẹ̀yìn ahọ́n
(xviii) Káà ẹnu
(viii) Òlélé
(xix) Àjà ẹnu
(ix) Tán-án-ná
(xx) Eyín ìsàlẹ̀
(x) Eyín òkè
(xxi) Ahọ́n
(xi) Ẹ̀dọ̀ fóró
B
Ìró Kọ́nsónáǹtì |
Afipè àsúnsí |
Afipè Àkànmọ́lẹ̀ |
/r/ |
iwájú ahọ́n |
erìgì |
/kp/ |
ètè ìsàlẹ̀ àti ẹ̀yìn ahọ́n |
ètè òkè àti àfàsé |
/ g / |
ẹ̀yìn ahọ́n |
àfàsé |
/ d / |
iwájú ahọ́n |
erìgì |
/ j / |
àárín ahọ́n |
àjà ẹnu |