Question 4
(a) Kí ni ọ̀rọ̀-asopọ̀?
(b) Kọ àpẹẹrẹ ọ̀rọ̀-asopọ̀ márùn-ún kí o sì lo ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn níṅú gbólóhùn.
Observation
Candidates were required to define conjunctions/disjunctions in (a), mention 5 examples of conjunctions/disjunctions and use each of them in sentences in (b). 
   
 Ọ̀rọ̀-asopọ̀ ni àwọn wúnrẹ̀n tí à ń lò láti so ọ̀rọ̀ tàbí gbólóhùn pọ̀.
  
(bi)	Àpẹẹrẹ ọ̀rọ̀-asopọ̀		
	 
		
    (i)	pẹ̀lú	
		
          (ii)	òun
				
          (iii)	àti	
					 
          (iv)	sì		
		 
    (v)	àyàfi/àfi	
					 
    (vi)	ańbèlèǹté/ańbèlèǹtàsé/ ańbọ̀sìbọ́sí/ańbọ̀sì
    (vii)	ṣùgbọ́n/àmọ́
    (viii)	yálà...tàbí
    (ix)	bẹ́ẹ̀ ni
    (x)	tàbí/àbí
    
Majority of the candidates recalled the definition of conjunction/disjunction in (a), gave accurate examples in (b) and also used the conjunctions/disjunctions in sentences. Candidates’ performance in question 4 was commendable.