Yoruba Paper 2 WASSCE (SC), 2019

Question 5

 

 

Fa awẹ́ gbólóhùn afarahẹ inú ọ̀kọ̀ọ̀kan gbólógùn wọ̀nyí yọ kí o sì sọ irúfẹ́ awẹ́-gbólóhùn tí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọ́n jẹ́.

Observation

 

Candidates were expected to identify the subordinate clause in each sentence and mention the type of each subordinate clause identified.

Awẹ́-gbólóhùn afarahẹ

Irúfẹ́ awẹ́-gbólóhùn tí ó jẹ́

(a) kí n tó dé

Aṣàpọ́nlé

(b) tí mo mu

Aṣàpèjúwe

(d)láti tún un tà

Aṣàpọ́nlé

(e)pé n kò tíì jẹun

Àsọdorúkọ

(ẹ) tí bàbá rà

Aṣàpèjúwe

(f)pé wọ́n tètè dé

Àsọdorúkọ

Most candidates who attempted this question find láti tún un ta difficult to describe appropriately as aṣàpọ́nlé.The others were relatively simple for them to describe.