Question 2
Lo bátànì ìhun sílébù láti fi pín ọ̀kọ̀ọ̀kan ọ̀rọ̀ wọ̀nyí:
(a) pándọ̀rọ̀;
(b) kedere;
(d) Ọláìítán;
(e) Láníyọnu;
(ẹ) Akéréle;
(f) Babalọ́lá;
(g) Ọlálékan;
(gb) Adéróunmú;
(h) kọ̀ǹkọ̀;
(i) Ajéèégbé.
Observation
Candidates were required to use syllabic pattern for syllabic analysis of the given data:
|
Ọ̀rọ̀ |
Bátànì Ìhun Sílébù |
a. |
Páńdọ̀rọ̀ |
KF/N/KF/KF |
b. |
Kedere |
KF/KF/KF |
d. |
Ọláìítán |
F/KF/F/F/KF |
e. |
Láníyọnu |
KF/KF/KF/KF |
ẹ. |
Akéréle |
F/KF/KF/KF |
f. |
Babalọlá |
KF/KF/KF/KF |
g. |
Ọlálékan |
F/KF/KF/KF |
gb. |
Adéróunmú |
F/KF/F/F/KF |
h. |
Kọ̀ǹkọ̀ |
KF/N/KF |
i. |
Ajéèégbé |
F/KF/F/F/KF |
Many of the candidates who attempted this question could not use the syllabic pattern for syllabic analysis of the given data, this led to poor performance.