Question 8
Sọ̀rọ̀ lórí ìwúlò Ègè
Observation
Candidates were required to discuss the importance of Ègè Dídá as evident in the excerpt.
Iwúlò Ègè:
(i) Ègè dídá kún fún ìjìnlẹ̀ ọ̀rọ̀, ọgbọ́n àti ọ̀rọ̀ apanilẹ́rìn-ín
(ii) Ègè dídá máa ń dá ènìyàn lára yá
(iii) Ó máa ń rán ènìyàn léti ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ti kọ́já tàbí ìtàn tí ó fara sin láti fi kọ́ àwọn èrò ìwòran lẹ́kọ̀ọ́
(iv) Ó máa ń mú orí ẹni wú/yá
(v) Ó jẹ́ ọ̀nà àtijẹ fún àwọn tí ó fi ń ṣe iṣẹ́ ṣe
(vi) Ó máa ń fọ àwujọ́ mọ́ nípa ṣíṣe àfihàn ìwà ìbàjẹ́/kòtọ́ ní àwùjọ
(vii) Ó máa ń ki ènìyàn nílọ̀ lórí ìwà kòtọ́
(viii) Ègè wà fún ayẹyẹ gbogbo láti mú ìgbádùn bá àwùjọ
(ix) Ó wúlò fún ìpolon̄go onírúurú nǹkan láwùjọ Yorùbá
(x) Àwọn Yorùbá máa ń lo Ègè gẹ́gẹ́ bí orin amúṣẹ́yá.
Only a few candidates attempted this question. Their responses to this question portrayed failure to study the text.