Question 2
- Kí ni fóònù?
- Kí ni fóníìmù
- Ṣe àdàkọ àwọn lẹ́tà wọ̀nyí ní ìlànà fóníìmù:
(i) ṣ (vi) un
(ii) ọ (vii) y
(iii) ẹ (viii) p
(iv) j (ix) in
(v) gb (x) l
Observation
Candidates were required to define phone in (a), phoneme in (b) and transcribe the letters in (d)
(a) Fóònù: Èyí ni ìró kọ̀ọ̀kan tí a máa ń gbé jáde nígbà tí a bá ń ṣe afọ̀.
(b) Fóníìmù: Èyí ni àwọn ìró tí wọ́n bá lè fi ìyàtọ̀ ìtumọ̀ hàn láàrin ọ̀rọ̀ kan àti òmíràn.
(d) Àdàkọ àwọn ìró:
S/N |
ÌRÓ |
ÀDÀKỌ ÌRÓ |
I |
ṣ |
/ʃ/ |
ii |
ọ |
/ɔ/ |
iii |
ẹ |
/ɛ/ |
iv |
J |
/ʤ/ /ɉ/ |
v |
Gb |
/g҇b/ |
vi |
Un |
/ũ/ |
vii |
Y |
/j/ |
viii |
P |
/k҇҇p/ |
ix |
In |
/ĩ/ |
x |
L |
/l/ |
Most candidates who attempted this question failed because they mistook fóònù, a unit of sound in phonology, for phone in telecommunication. They also missed out in transcription, thus leading to their poor performance in this question.