Question 8
Mẹ́nu ba ohun tí ègè dídá máa ń dá lé lórí
Observation
The expected points are:
Àwọn ohun tí Ègè Dídá máa ń dá lé lórí:
(i) Ìbà jíjú ni ìbẹ̀rẹ̀ eré
(ii) Fífi ara ẹni hàn (oríkì adígè, oríkì ìdílé rẹ̀, oríkì orílẹ̀ rẹ̀)
(iii) Oríkì àwọn èrò ìwòran
(iv) Oríkì ọba, ìjòyè àti àwọn ènìyàn pàtàkì pàtàkì ní ìlú
(v) Onírúurú ìmọ̀ràn fún àwọn ènìyàn
(vi) Oríṣíríṣi ìtàn àtayébáyé
(vii) Ṣíṣe àpọ́nlé àwọn ènìyàn
(viii) Bíbú àwọn tí èébú tọ́ sí
(ix) Ṣíṣe ẹ̀fẹ̀ àti àwàdà
(x) Ṣíṣe onírúurú ìwúre
Candidates are required to mention the specific speech art of Ẹ̀gè Dídá.
Most candidates relied on their previous knowledge of the verbal art performance rather than answering the question based on the text.