Question 5
Fa àwọn àpólà orúkọ yọ nínú àwọn gbólóhùn wọ̀nyí kí o sì sọ iṣẹ́ tí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ṣe.
(a) Ọmọ rẹ́ dé ní àná.
(b) Dúpẹ rí ọ.
(d) Ṣọlá máa ń ná owó
(e) Bámidélé kò ra aṣọ.
(ẹ) Jádesọ́lá wọ bàtà funfun.
Observation
Àpólà orúkọ àti iṣẹ́ tí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọ́n ṣe nínú gbólóhùn
S/N |
Àpólà Orúkọ inú gbólóhùn |
Iṣẹ́ tí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọ́n ṣe |
a |
Ọmọ rẹ̀, àná |
Olùwà, Àbọ̀ (fún ọ̀rọ̀-atọ́kùn ní) |
b |
Dúpẹ́, ọ |
Olùwà, Àbọ̀ |
d |
Ṣọlá, owó |
Olùwà, Àbọ̀ |
e |
Bámidélé, aṣọ |
Olùwà, Àbọ̀ |
ẹ |
Jádesọ́lá, bàtà funfun |
Olùwà, Àbọ̀ |
Only a few of the candidates who tackled this question were able to identify the noun phrases, some of them mistook nouns for noun phrases in sentences that the noun had a qualifier.