Question 7
Nínú oríkì “Ìran Alápà”, dárúkọ àwọn oríṣi Ògun àti àwọn ohun tí wọ́n fi ń bọ ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn.
Observation
Candidates were tasked to identify the different forms of the Ogun deity in this lineage and mention the symbol of worship for each of the different forms of the deity.
Oríṣi Ògún tí wọ́n bọ àti ohun tí wọ́n fi ń bọ wọn nínú oríkì “Ìran Alápà”
S/N |
Oríṣìí Ògún |
Ohun tí wọ́n fi ń bọ ọ̀kọ̀ọ̀kan wọ́n |
i |
Ògún Ènírá |
Ẹran ajá |
ii |
Ògún Ajerò |
Àgbò |
iii |
Ògún enígbàjámọ̀ |
Irun |
iv |
Ògún alápatà |
Ẹ̀jẹ̀ ẹran |
v |
Ògún eníkọlà |
Ìgbín |
vi |
Ògún gbẹ́nàgbẹ́nà |
Oje igi |
vii |
Ògún alágbẹ̀dẹ |
Èédú arọ́ |
The candidates who attempted this question performed poorly. This shows poor knowledge of the set text.