Question 12
(a) Ṣeàlàyé ní ṣókí ìhà tí àwọn Yorùbá kọ sí ọ̀ràn dídá láyé àtijọ́.
(b) Ṣeàlàyé ìjìyà tàbí ìdájọ́ ìbílẹ̀ fún ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wọ̀nyí:
(i) Ìpànìyàn
(ii)Àgbèrè ṣíṣe
iii) Olè jíjà
(iv) Èké Ṣíṣe
(v) Jìbìtì lílù
Observation
Candidates were required to describe the view of the Yoruba traditional society to crime in the olden days in (a) and to state the punishment for each of the crimes listed in (b).
(a) ÌhàtíàwọnYorùbákọsíọ̀ràndídáláyéàtijọ́
Yorùbá ní ìgbàgbọ́ nínú ìdájọ́ òdodo. Gbogbo ọ̀ràntíènìyànbádá ló ní ìdájọ́/ìjìyà lábẹ́ ètòìṣàkósoìlú. Wọn kì í fi ẹjọ́ ṣègbèrárá.
(b) Ìjìyà/ìdájọ́ ìbílẹ̀ fúnọ̀kọ̀ọ̀kanàwọnẹ̀ṣẹ̀ tíènìyànlèdá
S/N |
Ẹ̀ṣẹ̀ |
Ìjìyà tàbí ìdájọ́ìbílẹ̀ |
i |
Ìpànìyàn |
Bíbẹ́ orí ọ̀daràn sí ìdí Ògún/síso ọ̀daràn rọ̀ sínú igbó |
ii |
Àgbèrè ṣíṣe |
Tí ó bá jẹ́ onílélọ́kùnrin, wọn yóò ta á lójì. |
iii |
Olè jíjà |
Wọ́n lè fi olè sínú túúbú. |
iv |
Èké Ṣíṣe |
Wọ́n lè ku eérú èké lé e lórí nígban̄gba. |
v |
Jìbìtì lílù |
Sísan owó ìtanràn; dídá owó padà. |
vi |
Kí ọba tàpá sí òfín ìlú |
Wọ́n lè ní kí ọba ṣígbá-ìwàwò/ṣe bíọkùnrin. |
Only a few of the candidates who attempted this question grasped the requirement of the question.