Yoruba Paper 2 WASSCE (PC), 2022

Question 8


Ṣàlàyé lórí ohun tí adígè sọ nípa igbó orò

Observation

 

Candidates were expected todescribe the sacred forest as it is evident in the text.

          Ohun tí adígè sọ nípa igbó Orò:

(i)      Igbó Orò ni ojúbọ Orò máa ń wà.
(ii)      Wọ́n máa ń sin àwọn ọ̀daràn wọ igbó Orò.
(iii)     Arúfin tí wọ́n bá sìn wọ inú igbó Orò kò lè padà wá mọ́.
(iv)     A lè ṣe alábàápàdé oríṣiríṣi òkùtù ènìyàn (òkú tí kò ní orí) nínú igbó Orò.
(v)      Igbó Orò ni wọ́n máa ń mú àwọn afurasí gẹ́gẹ́ bí oṣó tàbí àjẹ́ lọ láti búra bóyá wọ́n ṣe ibi láàrin ìlú
(vi)     Kì í ṣe gbogbo ènìyàn ni ó lè dé ojúbọ Orò nínú igbó Orò
(vii)    Nínú igbó Orò ni wọ́n ti máa ń bẹ̀rẹ̀ ọdún Orò
(viii)   Inú igbó Orò ni wọ́n máa ń parí ọdún Oró sí

Only a few candidates attempted this question.  Their responses to this question portrayed failure to study the text.