Yoruba Paper 2 WASSCE (SC), 2023

Question 2: Lo àmì ohùn láti fi ọ̀rọ̀ mẹ́tamẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ han fún ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn wúnrẹ̀n wọ̀nyi              

  1. ọkọ
  2. igba
  3. ara
  4. ọwọ
  5. agbọn

Observation

 

S/N

WÚNRẸ̀N

Ọ̀RỌ̀ MẸ́TA Ọ̀TỌ̀Ọ̀TỌ̀

(a)

ọkọ

ọkọ, ọkọ́, ọkọ̀, ọ̀kọ́

(b)

igba

igba, igbá, igbà, ìgbà, ìgbá

(d)

ara

ara, ará, arà, àrà, àrá

(e)

ọwọ

ọ̀wọ, ọwọ́, ọwọ̀, Ọ̀wọ̀/ọ́wọ́, ọ̀wọ́

(ẹ)

agbọn

àgbọn, agbọ́n, agbọ̀n, àgbọ̀n

Candidates were required to give 3 examples of Yorùbá words from the  given data using tones marks to diffrentiate the words.
Some candidates who attempted this question failed to use the appropriate tone marks to differentiate the words thereby losing marks, this led to poor performance