Yoruba Paper 2 WASSCE (SC), 2023

Question 3

Dárúkọ mẹ́wàá nínú àwọn fáwẹ̀lì èdè Yorùbá. B. a. [ i ]: fáwẹ̀lì àhánupè/òkè iwájú pẹrẹsẹ.
Àkíyèsí: Àkámọ́ onígun pọn dandan

Observation

This question requires the candidates to decribe 10 Yorùbá vowels using the square bracket.

 

 

Dídárúkọ mẹ́wàá nínú àwọn fáwẹ̀lì èdè Yorùbá

S/N

Fáwẹ̀lì

Dídárúkọ rẹ̀

a

[e]

Fáwẹ̀lì àhánupè/òkè iwájú pẹrẹsẹ

b

[ɛ]

Fáwẹ̀lì àyánudíẹ̀pè/ẹ̀bádò iwájú pẹrẹsẹ

d

[a]

Fáwẹ̀lì àyánupè/odò àárín pẹrẹsẹ

e

[ɔ]

Fáwẹ̀lì àyánudíẹ̀pè/ẹ̀bádò ẹ̀yìn roboto

[o]

Fáwẹ̀lì àhánudíẹ̀pè/ẹ̀bákè ẹ̀yìn roboto

f

[u]

Fáwẹ̀lì àhánupè/òkè ẹ̀yìn roboto

g

[ĩ]

Fáwẹ̀lì àránmúpè àhánupè òkè pẹrẹsẹ

gb

[ɛ͂]

Fáwẹ̀lì àrànmúpè àyánudíẹ̀pè/ẹ̀bádò iwájú pẹrẹsẹ

h

[ã]

Fáwẹ̀lì àránmúpà àyánupè/odò àárín pẹrẹsẹ

i

[ɔ͂]

Fáwẹ̀lì àránmúpè àyánudíẹ̀pè/ẹ̀bádò ẹ̀yìn roboto

j

[ũ]

Fáwẹ̀lì àhánupè/òkè ẹ̀yìn roboto

 

Most candidates performed woefully in this question. Many of them  failed to use the square bracket, rather they used the slanting bracket and also missed out on the appropriate decription of the vowels.