Yoruba Paper 2 WASSCE (PC 2ND), 2018

Question 10

    Nínú ewì “Obìnrin Ológo”, kí ni àwọn ohun tí Akéwì sọ pé kì í jẹ́ kí obìnrin di ológo?


Observation

Candidates were required to mention the various vices that could prevent a woman from becoming a glorious woman in “Obìnrin Ológo”.

Àwọn ohun tí akéwì sọ pé kì í jẹ́ kí obìnrin di ológo nínú ewì “Obìnrin Ológo” ni:

  1. Kí obìnrin máa sá fún ẹni tó lè ṣe é lóore.
  2. Ìwà àgbèrè.
  3. Kí obìnrin máa bú ènìyàn.
  4. Èpè ṣíṣẹ́.
  5. Òògùn ìkà ṣíṣe.
  6. Kí obìnrin máa lo orí ọkọ rẹ̀.
  7. Kí obìnrin má gbà fún Olúwa.
  8. Kí obìnrin má tọ́jú ọkọ àti ọmọ rẹ̀.
  9. Àìfi ìwà ọ̀yàyà bá ẹbí ọkọ lò.
  10. Àìkọbíara sí àdúrà gbígbà.

General guesses were made on various vices that can prevent a woman from being glorious but not as evident in the written poem.