Question 2
Ṣe àpèjúwe ipò àlàfo tán-án-ná; ibi ìṣẹnupè àti; ọ̀nà ìṣẹnupè ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn kọ́nsónáǹtì wọ̀nyí: (a) [k] (b) [w] (d) [t] (e) [j] (ẹ) [d].
    
Observation
Candidates were required to identify the state of the glottis, place of articulation and manner of articulation for each of the consonants above.
 Ìró Kọ́sónsónáǹtì  | 
      
 Ipò    àlàfo   | 
      
 Ibi ìṣẹnupè  | 
      
 Ọ̀nà ìṣẹnupè  | 
    
[k]  | 
      Àìkùnyùn  | 
      àfàfàsépè  | 
      àsénupè  | 
    
[w]  | 
      Àìkùnyùn  | 
      àfàfàséfètèpè  | 
      àsséèsétán  | 
    
[t]  | 
      Àìkùnyùn  | 
      àfèrìgìpè  | 
      àsénupè  | 
    
[j]  | 
      Akùnyùn  | 
      àfàjàpè  | 
      àséèsétán  | 
    
[d]  | 
      Akùnyùn  | 
      àfèrìgìpè  | 
      àsénupè  | 
    
Candidates’ performance was above average.