Question 2
Ṣe àpèjúwe ipò àlàfo tán-án-ná; ibi ìṣẹnupè àti; ọ̀nà ìṣẹnupè ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn kọ́nsónáǹtì wọ̀nyí: (a) [k] (b) [w] (d) [t] (e) [j] (ẹ) [d].
Observation
Candidates were required to identify the state of the glottis, place of articulation and manner of articulation for each of the consonants above.
Ìró Kọ́sónsónáǹtì |
Ipò àlàfo |
Ibi ìṣẹnupè |
Ọ̀nà ìṣẹnupè |
[k] |
Àìkùnyùn |
àfàfàsépè |
àsénupè |
[w] |
Àìkùnyùn |
àfàfàséfètèpè |
àsséèsétán |
[t] |
Àìkùnyùn |
àfèrìgìpè |
àsénupè |
[j] |
Akùnyùn |
àfàjàpè |
àséèsétán |
[d] |
Akùnyùn |
àfèrìgìpè |
àsénupè |
Candidates’ performance was above average.